ISE ISENBAYE

Download Report

Transcript ISE ISENBAYE

ISE AGBE ATI ISE ILU LILU
ORIKI ISE ISENBAYE
 Ise isenbaye naa ni a mo si ISE ABINIBI.
 O je ise ti a jogun lati owo awon baba nla wa
APEERE ISE ISENBAYE
• Owo sise
Ona sise
Ope kiko
Ise ila kiko
•Ise agbe ,
Ise ode,
Ise ilu lilu, Ise agbede,
• Ise aro dida, Ise irun didi
ISE AGBE
 Ise agbe je ise oko riro, ohun ogbin gbingbin ati eran
osin sinsin .
• AGBE AYE ATIJO
• ORISIIRISII AGBE AYE ATIJO
•AGBE ALAROJE– o n da oko kekere fun ohunje jije.
•Apeere ere oko re : ogede, agbado, isu. ege, eree, ata ati ewebe.
•AGBE OLOKO NLA- o n da oko nla lati gbin ohun jije ati igi owo
bii koko, ope, kofi, obi, orogbo, ati igi roba.
•Won maa n lo eru ati iwofa fun ise loko.
•Awon iyawo, omo ati ebi naa maa n ran won lowo.
ISE AGBE ODE - ONI
 Awon agbe ode- oni ni awon ti o n lo awon ero igbalode




lati sise agbe
ORISIIRISII AGBE ODE – ONI.
Agbe alaroje –won da oko ohunjije lati pese fun ebi won.
Agbe oloko nla –awon wonyii n da oko lati fi sise se.
Agbe olohun osin – awon ti o n sin eranko bii Maluu.
Adiye ati Elede.
OHUN ELO ISE AGBE
 OHUN ELO ISE AGBE AYE ATIJO
.
Oko,
Ada , Akoro, Aake, ati Obe
•OHUN ELO ISE AGBE ODE-ONI
•Oogun ajileEro igbalode – Katakata,ero irole ati ikobe.
 Irugbin ti kii pe so.
Oogun ajile.
ORISIIRISII OKO
 OKO EGAN – Ile aginju ti a sese da. Ile oloraa o dara fun
gbingbin Igi owo bii koko orogbo, obi, roba ati ope.
 OKO ODAN – Ile pupa, o dara fun gbingbin ohunje bii
agbado, ege, isu, eree, okaa-baba,owu, anamo. Egunsi,
ata, ila ati ewebe.
 OKO ODO/AKURO – Ile olomi. Oko eba odo ni, o dara
fun gbingbin agbado, ogede, ata,ila ati ewebe bii efo ati
ewedu.
ITOJU IRE OKO
•Ni aye atijo inu aba tabi aka ni won maa n toju ire oko
si.
•NI aye ode-oni oogun ni won maa n fi si ire oko ki o
ma baa ni kokoro.
 PATAKI ISE AGBE
 Ipese ohun jije fun awujo.
 Ipese ise fun awon eniyan.
 Ipese ohun elo fun awon ile-ise gbogbo.
 Ipawo wole si apo ijoba, paapaa lori awon ohun ti a
ba fi sowo si oke okun.
ILU LILU
 Iran Ayan ati omo ti won toro lowo Ayangalu lo n lulu.
 Oruko to awon onilu maa n je ni Ayanbunmi,
Ayanleke, Ayandele, Alayanande, Ayangbemi , abblo.
 Ise amuluudun ni ise ilu lilu.
DIE NINU ORISIIRISII ILU TI O WA NILE YORUBA.
 Dundun, Gangan, Adamo, Ibembe, Igbin, Agere, Ipese
Osugbo, Agogo, Apepe, Sanba, Sakara, Agidigbo, Aran
ati Kiriboto.
OHUN ELO ILU
 Igi, awo, ati osan
 PATAKI ILU LILU
 Fun ayeye – b.a isomoloruko, isinku agba, igbeyawo,





isile. Ati iwuye
Fun ijosin – b.a bata fun sango.
Fun ipolowo oja.
Fun kiki oba.
Fun ogun - imoriya ati itani-lolobo.
Fun ikede.
ISE SISE
 1.Dahun ibeere ti o wa ni oju ewe 105 (pg 105) iwe
Simplified Yoruba L1 For J.S 1. lati owo Adewoyin S.Y.
 2. Ya orisii ilu marun-un ti o ba wu o.