NIGERIAN LANGUAGE YORUBA 2ND WEEK.

Download Report

Transcript NIGERIAN LANGUAGE YORUBA 2ND WEEK.

IHUN GBOLOHUN GBOLOHUN
A.Orisi ihun gbolohun
1.Ihun nipa apola.
Ihun nipa awe.
IHUN GBOLOHUN
APOLA
AWE
GBOLOHUN
Apola oruko
1.Mo
2.Ode
Apola ise
Lo si Eko
N kun eran
D. Ihun nipa awe gbolohun
Gbolohun onibo :eyi pin si ona meji
AWE GBLOHUN
Afarahe
1.Afarahe asaponle
2.Afarahe asodoruko
3.Afarahe asapejuwe
Olori awe gblohun
E. Abuda awe gbolohun
1.Awe gbolohun le je ipede ti oni oluwa ati ohun ti oluwa se.
Apeere:Adejoke mu omi.
Awon akekoo jeun.
2.O le ni ju apola oruko ati apola ise kookan lo.
3.Awe gbolohun le da duro ki o niitumo.Apeere:Omi ero naa mo.
4.Awe gbolohun miran leda duro ki oni itumo.
5.Awe gbolohun le da duro bii odidi gbolohun,iru awe gbolohun bee ni
a n pe ni olori awe gbolohun.Bi apeere:Won gba,Ade mo.
6.Opolopo awon gbolohun abode ni o le se ise gbolohun,sugbon kii se
gbogbo
awe gbolohun lo le duro bii gbolohun.
Olori awe gbolohun:eyi ni awe gbolohun ti o le da duro,ki o si ni itumo
Awe.
Awe gbolohun afarahe:awe gbolohun afarahe ni apa gbolhun onibo tabi alakanpo ti ko
Da duro.
Orisi awe gbolohun afarahe.
1.AwegbolohunAsaponle.
2. Awe gbolohun Asapejuwe.
3.Awe gbolohun Asodoruko.
Iyato laarin Apola ati awe gbolohun.
1.Apola le ni oro –ise tabi ki oma ni,dandan ni oro ise fun awe gbolohun.
2.Apola ko le da duro ki o fun wani itumo kikun sugbon awe gbolohun le
da duro.
3.Apola le waninu awe gbolohun ti oni itumo.
4.Awe le je odidi gbolohun to kun.
ISE ASE TI LE WA.
1.Ki ni gbolohun?
2.Ona melo ni gba wo ihun gbolohun?So awon ona wonyii.
3.So abuda meta ti awe gbolohun le ni.
4.So orisi awe gbolohun ti o wa,pelu apeere kookan.