Transcript EKO ILE

EKO ILE
Eko ile ni eko iwa hihu,iwa rere,iwa toto,iwa to ye ti obi
fi nko omo lati kekere.
Apeere eko ile ni:
1.Ikini :igbakugba ni a le ki eniyan bii,aaro,osan,ale,irole.
2.Itoju ile ati ara:bii iwe wiwe,aso fifo ile titun se.
3.Ibowo fun agba ati alejo sise.
4.Iwa omoluabi:lara iwa omoluabi ni,ife siomo enikeji,ibowo,
5.ibomowi.
ISE ASE TI LE WA
1.Ki ni eko ile?
2.Ko iwa omoluabi marun.
3.Ko orisi ikini marun ti o mo.